Oluso Ayemi

Post by achazua lucky
2022-03-29
Oluso Ayemi image
556      113   
1    0      

achazua lucky

Listen to Audio

Please share
This is a prayer/thanksgiving song composed and arranged by Lucky Achazua

Call: Oluwa eyin l'oun so mi 

Res: Oba rere

Call: Eyin l'oun so mi

Res: Oba rere 

All: Eyin l'oun so mi

Jehovah Nissi sa l'oun so mi

Oba rere

Verse : 1

Ero ota l'aye ti awa

Bipe ka'waye wa toro je ni

Ero ota l'aye ti awa

Bipe ka'waye wa s'erun ni

Olowo bi oni 

Odi dandan kan l'epa re

Oko'le bi o ko 

Odi dandan kan l'epa re

Won l'eni titi 

Oluwa ni ko gba fun won

Won l'epa titi

Oluwa ni ko gba fun won

Won gb'ogun titi

Oluwa f'ajulo han won ooo

Eyin sa l'oun so mi 

Jehovah Nissi sa l'oun so mi

Oba rere

Verse: 2

Many are the afflictions of the righteous 

Jehovah you delivered them

Many are my afflictions you delivered me

Ogun n'ile aye 

Afi k'olorun yo'nu si ni

Ogun n'ile aye

Afi k'olorun ko ni yo

Won l'eni titi

Olorun ni ko gba fun won

Won l'epa titi

Olorun ni ko gba fun won

Won gb'ogun titi

Oluwa f'ajulo han won oo

Eyin sa l'oun so mi

Jehovah Nissi sa l'oun so mi

Oba rere

Call: Oluwa eyin l'oun so mi 

Res: Oba rere

Call: Eyin l'oun so mi

Res: Oba rere 

All: Eyin l'oun so mi

Jehovah Nissi sa l'oun so mi

Oba rere

Bridge :

Call: K'ini m'ba fi san ore baba oo

Res :Biko s'ope 

Call: K'ini m'ba fi san f'anu re l'aye mi

Res: Biko s'ope

Call: K'ini m'ba fi san f'abore l'ori mi

Res: Biko s'ope

Baba mi t'ewo gb'ope

L'ori aye mi

L'ori ebi mi

L'ori omo mi



Please share